BY OGUNYEMI OLUSEGUN T.
Read Psalm 119
1. Thank the Lord for blessing you with help you do not deserve or qualify for.
2. My Father, my Father, by faith I activate all inactive and dormant helpers assigned for my life and destiny.
3. It is written, ‘only believe.’ Therefore, I believe help is locating me this season.
4. My Father, it is written in Your word that the just shall live by his faith. By my faith, I declare that I am the next in line to experience help.
5. My help cometh from the Lord. By faith, I collect my help, Amen.
YORUBA EDITION
1. Dupe lowo Olorun ti o bukun re pelu iranlowo ti o ko to si, tabi o ko ye fun.
2. Baba mi, nipase igbagbo mo ji gbogbo awon oluranlowo ti ko sise ati eleyi ti o nsun ti a yan fun aye mi ati ayanmo mi dide
3. A ko wipe, “sa gbogbo.” Fun idi eyi mo gbagbo pe iranlowo nwa mi bo
ni akoko yi.
4. Baba mi, Baba mi, a ko ninu oro re wipe, “olododo ni yoo ye nipa igbagbo.” Nipa igbagbo mi, mo pase wipe emi ni o kan lati ni iriri
iranlowo.
5. Iranlowo mi ti owo Oluwa wa, nipa igbagbo mo gba iranlowo, Amin.
Jesus is Lord no controversy.
SPONSORED ADS 👇👇
SPONSORED ADS 👇👇


























No comments