BY OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
Email: ogunyemiolusegun1@gmail.com
PRAY WITH PSALM 23:2,3
1. Lord, I thank You for the covenant You made with my life. Sing a new song to the Lord.
2. I remove my name, picture and everything used to represent me on the altar of darkness in the name of
Jesus.
3. Divine help that will give me unbelievable goodnews, I connect with it in the name of Jesus.
4. Call the God of Mercy, send the angel of goodnews to me.
5. The generational secrets that is wasting my efforts be revealed to me in the name of Jesus.
YORUBA EDITION
1. Oluwa mo yin O fun majemu rere ti o ba aiye mi da. Ko orin iyin tuntun si Oluwa.
2. Mo yo oruko mi, aworan mi ati gbogbo oun ti a fi se asoju mi lori pepe okunkun l'oruko Jesu.
3. Iranwo atokewa ti yio funmi ni iroyin ayo to soro gbagbo, mo s'opo mo l'oruko Jesu.
4. Pe Olorun aanu, ran awon angeli
oniroyin ayo si mi l'oni l'oruko Jesu.
5. Asiri irandiran to nfi akitiyan mi sofo tu funmi pelu ina.
Jesus is Lord no controversy
No comments