By Pastor Ogunyemi Olusegun Timothy
Email: ogunyemiolusegun1@gmail.com
PRAY WITH PSALM 29
1. Praise God to thank Him because there is no king like Him. Sing to the Lord.
2. Blood of Jesus, cleanse our land from every guilt of blood.
3. Everything inside of me that pushes me to err, Blood of Jesus consume it.
4. Every wind of darkness blowing contrary to the tree of Joy in my life, be silenced in the name of Jesus.
5. Every storm sent to me from the dream to steal my garment of glory, be silenced in the name of Jesus.
YORUBA EDITION
1. Yin Oluwa lati dupe l'owo Re pe ko si oba to da bi Re, ko orin si Oluwa.
2. Eje Jesu, fo ile wa mo kuro l'owo gbogbo ebi eje.
3 . Ohun gbogbo ninu mi, ti o nti mi sise, Eje Jesu gbemi.
4. Gbogbo afefe okunkun to nfe lodi si igi ayo mi, e dakeje l'oruko Jesu.
5 . Iwo iji ti a ran simi l'oju orun, lati k'aso ola kuro l'ara mi, dakeje l'oruko Jesu.
JESUS IS LORD NO CONTROVERSY
No comments