BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
1. Lord, I thank You because You are greater than authority of the devil.
2. Lord, forgive me for all my disobedience to all Your ordinances.
3. Anointing for authority in the Word fall on me in Jesus name.
4. Lord, use my next journey to confuse my enemies in Jesus' name.
5. Key to the city where I am, God of Mercy hand it over to me. Amen.
YORUBA EDITION
1. Oluwa, mo yin O pe o ga ju gbogbo ase ibi gbogbo lo.
2. Oluwa, darijimi fun aigboran si awon ilana Re l'oruko Jesu.
3. Ororo ase oro, da le mi l'ori l'oruko Jesu.
4. Fi irinajo mi to kan ru ota mi l'oju l'oruko Jesu.
5. Kokoro ilu ti mo ti wa, Olorun aanu fi le mi l'owo l'oruko Jesu. Amin.
Jesus is Lord no controversy
No comments